Gómìnà Zulum Fidi Rẹ Mulẹ Pe Ọjà Jilli ti Di Tìtì Láti Ọdún Máàrún Sẹ́yìn Kí Ìkọlù Ọkọ̀ Òfurufú Tó Wáyé
Àwọn ọmọ ogun ojú òfurufú ti ilẹ̀ Nàìjíríà (NAF) ti bẹ̀rẹ̀ ìwádìí lórí ikú àwọn arálú nínú ìkọlù kan tó wáyé ní ọjà Jilli, tó wà láàárín ààlà ìpínlẹ̀ Borno àti Yobe . Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ológun sọ pé ibùdó àwọn agbésùnmọ̀mí ni wọ́n kọ lù, ìròyìn …